Sáàmù 125:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwa yóò dàbí òkè Síónì,tí a kò lè sí ní ìdí, bí kò ṣe pé ó dúró láéláé

Sáàmù 125

Sáàmù 125:1-3