Sáàmù 120:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Èmi ké pe Olúwa nínú ìpọ́njú mi,ó sì dámi lóhùn

2. Gbà mí, Olúwa, kúrò lọ́wọ́ ète èkéàti lọ́wọ́ ahọ́n ẹ̀tàn.

3. Kí ni kí a fi fún ọ?Àti kín kí a tún ṣe fún ọ,ìwọ ahọ́n ẹ̀tàn?

Sáàmù 120