Sáàmù 121:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò gbé ojú mi sórí òkè wọ̀n-ọn-nì—níbo ni ìrànlọ́wọ́ mi yóò ti wá

Sáàmù 121

Sáàmù 121:1-8