Sáàmù 119:55 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òru èmi rántí orúkọ Rẹ, Olúwa,èmi yóò sì pa òfin Rẹ mọ́

Sáàmù 119

Sáàmù 119:53-61