Sáàmù 117:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ yin Olúwa, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀ èdè;ẹ pòkìkí Rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn.

Sáàmù 117

Sáàmù 117:1-2