Sáàmù 115:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Kí ṣe fún wa, Olúwa kì ṣe fún wá,ṣùgbọ́n fún orúkọ Rẹ̀ ní a fi ògo fún,fún àánú àti òtítọ́ Rẹ.

2. Torí kí ní àwọn aláìkọlà yóò ṣe sọ pé,níbo ni Ọlọ́run wa wà.

Sáàmù 115