Sáàmù 115:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ṣe fún wa, Olúwa kì ṣe fún wá,ṣùgbọ́n fún orúkọ Rẹ̀ ní a fi ògo fún,fún àánú àti òtítọ́ Rẹ.

Sáàmù 115

Sáàmù 115:1-2