Sáàmù 112:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fi ìyìn fún Olúwa. Ìbùkún ni fún Ọkùnrin náà tí ó bẹ̀rù Ọlọ́run,tí ó ní inúdídùn ńlá sí àwọn òfin Rẹ̀.

Sáàmù 112

Sáàmù 112:1-10