Sáàmù 111:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbẹ̀rù Ọlọ́run ni ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọgbọ́n:òye dáradára ni yóò máa ṣe òfin Rẹ̀:ìyìn Rẹ̀ dúró láé.

Sáàmù 111

Sáàmù 111:8-10