Sáàmù 111:4-7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Ó ti ṣe iṣẹ́ ìyanu Rẹ̀, láti máa rántí: Olúwa ni olóore ọ̀fẹ́ àti pé ó kún fún àánú.

5. O ti fi oúnjẹ fún àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ̀:oun ń rántí májẹ̀mú Rẹ̀.

6. Ó ti fi hàn àwọn ènìyàn Rẹ̀ agbára isẹ́ Rẹ̀láti fún wọn ní ilẹ̀lérí ni ìní

7. Iṣẹ́ ọwọ Rẹ̀ jẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ́;gbogbo òfin Rẹ̀ sì dájú.

Sáàmù 111