1. Ìgbẹ́kẹ̀lé mí wà nínú Olúwa.Báwo ní ẹ̀yin o ṣe sọ fún ọkàn mi pé:“Fò gẹ́gẹ́ bi ẹyẹ lọ si orí òkè Rẹ.
2. Wò ó nítorí náà, ènìyàn búburú fa ọfà Rẹ̀;wọn ti ọfà wọn sí ojú okùnláti tafà níbi òjìjìsí àyà ẹni ìdúró ṣinṣin.
3. Nígbà tí ìpìlẹ̀ ba bàjẹ́kí ni olódodo yóò ṣe?”