Sáàmù 12:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ràn wá lọ́wọ́, Olúwa nítorí ẹni ìwà bí Ọlọ́run kò sí mọ́;Olótìítọ́ tí pòórá kúrò láàrin àwọn ènìyàn.

Sáàmù 12

Sáàmù 12:1-8