Sáàmù 102:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì wí pé;“Ọlọ́run mi, Má ṣe mú mi kúrò ní agbede-méjì ọjọ́ mi; ọdún Rẹ̀ ń lọ láti ìran dé ìran.

Sáàmù 102

Sáàmù 102:15-25