Sáàmù 1:5-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

5. Nítorí náà àwọn ènìyàn búburú kì yóò le è dìde dúró ní ìdájọ́,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ kì yóò le è dúró ní àwùjọ àwọn olódodo.

6. Nítorí Olúwa ń ṣọ́ ọ̀nà àwọn olódodo,ṣùgbọ́n ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú ni yóò ṣègbé.

Sáàmù 1