Sáàmù 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà àwọn ènìyàn búburú kì yóò le è dìde dúró ní ìdájọ́,bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ kì yóò le è dúró ní àwùjọ àwọn olódodo.

Sáàmù 1

Sáàmù 1:1-6