2. Ṣùgbọ́n ayọ̀ inú Rẹ̀ wà nínú òfin Olúwaàti nínú òfin Rẹ̀ ni ó ń ṣe àṣàrò ní ọ̀sán àti òru.
3. Ó dàbí igi tí a gbìn sí eti odò tí ń ṣàn,tí ń so èso Rẹ̀ jáde ní àkókò Rẹ̀tí ewé Rẹ̀ kì yóò Rẹ̀.Ohunkóhun tí ó dáwọ́lé,ni yóò máa yọrí sí rere.
4. Kò rí bẹ́ẹ̀ fún àwọn ènìyàn búburú!Wọn yóò dàbí ìyàngbò ọkàtí afẹ́fẹ́ ń fẹ́ dànù.