Sáàmù 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ayọ̀ inú Rẹ̀ wà nínú òfin Olúwaàti nínú òfin Rẹ̀ ni ó ń ṣe àṣàrò ní ọ̀sán àti òru.

Sáàmù 1

Sáàmù 1:1-6