Róòmù 6:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kírísítì ti jí dìde kúrò nínú òkú. Òun kò sì ní kú mọ́. Ikú kò sì lè ní agbára lórí rẹ̀ mọ́.

Róòmù 6

Róòmù 6:1-11