Róòmù 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwọ̀n ìgbà tí ògbólógbòó ara yín tó ń fẹ́ máa dẹ́sẹ̀ ti kú pẹ̀lú Kírísítì, àwa mọ̀ pé, ẹ̀yin yóò pín nínú ìyè titun rẹ̀.

Róòmù 6

Róòmù 6:5-12