Róòmù 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéṣe tí a kò fi ṣe búburú kí rere lè jáde wá? Bí àwọn kan tí ń fi ẹnu àtẹ́ sọ wí pé a ń sọ bẹ́ẹ̀; ti àwọn kan sì ń tẹnumọ́ ọn pé a sọ; àwọn ẹni tí ìdálẹ́bí wọn tọ́.

Róòmù 3

Róòmù 3:2-10