Róòmù 3:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí bí òtítọ́ Ọlọ́run bá di púpọ̀ sí ìyìn rẹ̀ nítorí èké mi, èéṣe tí a fi ń dá mi lẹ́jọ́ bí ẹlẹ́sẹ̀?

Róòmù 3

Róòmù 3:1-14