Òwe 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n wọn ò funra pé àwọn òkú wà níbẹ̀,pé àwọn àlejò rẹ̀ wà ní ìsàlẹ̀ ilẹ̀ isà òkú.

Òwe 9

Òwe 9:16-18