Òwe 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn òwe Sólómónì:Ọlọgbọ́n ọmọ ń mú inú baba rẹ̀ dùnṣùgbọ́n aláìgbọ́n ọmọ ń ba inú ìyá rẹ̀ jẹ́.

Òwe 10

Òwe 10:1-5