Òwe 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe kọ ọgbọ́n sílẹ̀, yóò sì dáàbò bò ọ́,fẹ́ràn rẹ̀, yóò sì bojú tó ọ.

Òwe 4

Òwe 4:3-10