Òwe 27:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìpara olóòórùn dídùn àti tùràrí ń mú ayọ̀ wá sínú ọkànbẹ́ẹ̀ ni inú dídùn láti ọ̀dọ̀ ọ̀rẹ́ ń wá láti inú ìmọ̀ràn tí ó Ṣàkóso.

Òwe 27

Òwe 27:1-18