Òwe 27:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe kọ ọ̀rẹ́ rẹ àti ọ̀rẹ́ baba rẹ sílẹ̀,má sì ṣe lọ sílé arákùnrin rẹ nígbà tí ìdàámú dé bá ọó sàn kí o jẹ́ aládúúgbò tí ó súnmọ́ ni ju arákùnrin tí ó jìnnà síni.

Òwe 27

Òwe 27:1-14