Òwe 26:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọ̀rọ̀ rẹ̀ tilẹ̀ fanimọ́ra, má ṣe gbà á gbọ́nítorí ìríra méje ni ó kún inú ọkàn rẹ̀.

Òwe 26

Òwe 26:23-26