Òwe 25:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò dára láti jẹ oyin àjẹjù,bẹ́ẹ̀ ni kò pọ́nni lé láti máa wá ọlá fún ara ẹni.

Òwe 25

Òwe 25:19-27