Òwe 25:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìsun tí ó di àbàtà tàbí kanga tí omi rẹ̀ bàjẹ́ni olódodo tí ó fi àyè gba ènìyàn búburú.

Òwe 25

Òwe 25:24-27