Òwe 25:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹni tí ó bọ́ra kalẹ̀ ní ọjọ́ tí òtútù mú,tàbí iyọ̀ tí a fi ra ojú egbò ọgbẹ́ tàbí bí ọtí kíkan tí a dà sórí sódàní ẹni tí ń kọ orin sí ọkàn tí ó bàjẹ́.

Òwe 25

Òwe 25:10-22