Òwe 25:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí eyín tí ó bàjẹ́ tàbí ẹṣẹ̀ tí ó rọni ìgbẹ́kẹ̀lé lórí aláìṣòótọ́ ní àsìkò ìdàámú.

Òwe 25

Òwe 25:18-23