Òwe 21:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwà ipá àwọn ènìyàn búburú yóò wọ́ wọn lọ,nítorí wọ́n kọ̀ láti ṣe ohun tí ó tọ́.

Òwe 21

Òwe 21:1-8