Òwe 16:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ti ènìyàn ni ìgbèrò inú ọkànṢùgbọ́n láti ọ̀dọ̀ Olúwa ni ìdáhùn ahọ́n ti ń wá.

2. Gbogbo ọ̀nà ènìyàn ni ó dà bí i pé ó dára lójú ara rẹ̀Ṣùgbọ́n Olúwa ló ń díwọ̀n èrò inú ọkàn.

Òwe 16