Òwe 17:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òkèlè gbígbẹ tòun tàlàáfíà àti ìdákẹ́jẹ́ sànju ilé tí ó kún fọ́fọ́ fún ẹran àti ìjà.

Òwe 17

Òwe 17:1-11