Òwe 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ètè olódodo ń tan ìmọ̀ kalẹ̀;ṣùgbọ́n kò rí bẹ́ẹ̀ fún ọkàn aláìgbọ́n.

Òwe 15

Òwe 15:1-11