Òwe 15:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilé olódodo kún fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìṣúra,ṣùgbọ́n èrè àwọn ènìyàn búburú ń mú ìyọnu wá fún wọn.

Òwe 15

Òwe 15:1-15