Òwe 12:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀lẹ ènìyàn kò sun ẹran tí ó pa lóko ọdẹṣùgbọ́n ẹni tí kì í ṣe ọ̀lẹ máa ń díwọ̀n ohun ìní rẹ̀.

Òwe 12

Òwe 12:18-28