Òwe 12:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olódodo ènìyàn máa ń ṣọ́ra láti dọ́rẹ̀ẹ́ṣùgbọ́n ọ̀nà àwọn ènìyàn búburú ń mú wọn sìnà.

Òwe 12

Òwe 12:24-28