Òwe 12:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ènìyàn rere gba ojú rere lọ́dọ̀ Olúwaṣùgbọ́n Olúwa kórìíra alárekérekè ènìyàn.

Òwe 12

Òwe 12:1-9