Òwe 12:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹ́ni tí ó fẹ́ ẹ̀kọ́ fẹ́ ìmọ̀,ṣùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí ó kórìíra ìbáwí jẹ́ aláìgbọ́n.

Òwe 12

Òwe 12:1-6