Òwe 11:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Aláìmọ̀ Ọlọ́run fi ẹnu rẹ̀ ba aládùúgbò rẹ̀ jẹ́,ṣùgbọ́n nípasẹ̀ ìmọ̀ Olódodo sá àsálà.

Òwe 11

Òwe 11:7-11