Òwe 1:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹnìkan tí ó bá fetí sí mi, yóò gbé láìléwuyóò sì wà nínú ìdẹ̀ra, láì sí ìbẹ̀rù ìpalára.”

Òwe 1

Òwe 1:32-33