Òwe 1:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìrìnkurìn àwọn aláìmọ́kan ni yóò pa wọ́nìkáwọ́-gbera aláìgbọ́n ni yóò pa á run;

Òwe 1

Òwe 1:25-33