Orin Sólómónì 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Omi púpọ̀ kò le paná ìfẹ́;Bẹ́ẹ̀ ni gbígbá omi kò le gbá a lọ.Bí ènìyàn bá fún ìfẹ́,ní gbogbo ọrọ̀ ilé rẹ̀,a ó kẹ́gàn rẹ̀ pátapáta.

Orin Sólómónì 8

Orin Sólómónì 8:2-9