Orin Sólómónì 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbé mi sí àyà rẹ bí èdìdìbí èdìdì lé apá rẹ;nítorí ìfẹ́ lágbára bí ikú,ìjowú sì le bí isà òkújíjò rẹ̀ rí bí ìjò iná,gẹ́gẹ́ bí ọ̀wọ́ iná Olúwa.

Orin Sólómónì 8

Orin Sólómónì 8:1-7