Orin Sólómónì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ ti gba ọkàn mi, arábìnrin mi, ìyàwó mi;Ìwọ ti gba ọkàn mipẹ̀lú ìwò ẹ̀ẹ̀kan ojú rẹ,pẹ̀lú ọ̀kan nínú ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn rẹ,

Orin Sólómónì 4

Orin Sólómónì 4:8-12