Orin Sólómónì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùfẹ́ mi ni tèmi èmi sì ni tirẹ̀;Ó ń jẹ láàrin àwọn lílì.

Orin Sólómónì 2

Orin Sólómónì 2:6-17