Bá wa mú àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀,àní àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ kékèkétí ń ba ọgbà àjàrà jẹ́,àwọn ọgbà àjàrà wa tó ní ìtàná.