Orin Sólómónì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òórùn ìkunra rẹ fanimọ́ra.Orúkọ rẹ rí bí ìkunra tí a tú jádeAbájọ tí àwọn wúndíá fi fẹ́ ọ.

Orin Sólómónì 1

Orin Sólómónì 1:1-5