Onídájọ́ 6:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì tún ṣe ohun tí ó burú ní ojú Olúwa, Ó sì fi wọ́n lé àwọn ará Mídíánì lọ́wọ́ fún ọdún méje.

Onídájọ́ 6

Onídájọ́ 6:1-8